Sei sulla pagina 1di 1

Ori Mi Apeere

Ori Mi Apeesin

Ori nle atideniran

Iwo ni agbeniku fosa

Ori loda agbe sile Aro

Ori loda aluko sode kosun

Ori loda lekeleke sode kefun

Ori ngbeni te fi dade Owo

Ori ni gbeni te fi tepa ileke

Ori ni gbeni te fin de lakuroje

Ori, orisa to ju orisa lo

Dakun gbemi

Ko ma pada leyin Mi

Ori Mi Apeere

Ori Mi Apeesin

Ori Mi tete gbemi oooo

Orisa tin gbeni bi Ori kosi

Kosi orisa tin dani GBE leyin Ori eni

Ori Mi Apeere

Ori nle atideniran

Iwo lagbeni Ku fosa.....

Ori agbe gbogbo wa oooo!!! Ase

O verdadeiro Orisa da Humanidade... Ori gbe mi ooo

Awolorisa Fomilayo deji lesi