Sei sulla pagina 1di 3

Bendecir los materiales

*PARA BENDECIR LOS MATERIALES*

*Omì (Agua)*

Alóló omi
Alòló omi
Àti wáyè e gúnnugún
Àti ròrun Àkàlàmàgbò
Ó n roni lójú tòkí
A dífá fún Òrúnmìlà
Ifá nlo rèé gbé Olómi tútù níyàwó
Ifá ló di èèwò Ifè
Èrìgì Àlò ò níí fi Olómitútù fún Ikú pa
T’òun Ikú ti di ìmùlè

*EPO (Aceite de palma)*

Gùrugùru guèguè
A dífá fún Epo
Tíí şe omo ìyá ebo
Epo gorí i rè ó d’ebo
Gùrugùru guèguè
Epo gorí i rè ó d’ebo
Gùrugùru guèguè

*IYO (sal)*

Ayoyogo

Ayoyogo

Ayoyogomangoman

Adifa fun Orunmila


Ifanloree mu iyo yora

Awa ti amu iyo yora oro ayo lobawa


Oro ibanujekan kiibaiyo

(nombre de la persona)
Ayoyogo

Ayoyogo

Ayoyogomangoman

*OYIN (MIEL)*

Okanran funfun ninini,


A difa fun Oyin igba ti n torun bo waye,
Ebo ni won ni ko se,
O si gbebo mbe o rub,
Ruru ebo eru atukesu,
E wa ba ni jebutu rere,
Nje a kii la oyin ka roju,
Oro oyin ko si dun.

*ATARE ( Pimienta )*

Atare kiiko ile re ki o ma


kun un ki iru-omo po bi omo atare
Ata ti a fi newure ni a npe ni atare
Nitori na atare iyo maa wi sun rere gbogbo wa fun
Atare kanna ni omo-araye npe ni oluya
Oluya ki o ya
Ni olola oniyi olorulo rere ninu aye
Olowo Olomo ati ohun rere gbogbo
Ki ara re ki o da
Ki ara re ki o ya
Ki ara re ki o mo
Ki ara re ki o ire gbogbo
Àse Olódùmarè

*OTÍ (Bebida con alcohol)*

Otura lalemu
Irete lale ra
AdiFafun Aranisan
Ti yoo mu Oti kan amulowo
Ebo ni ganó ni ko WAA sí
O gb'ebo, o ru'bo
Oti ola la o mu o
Aranisan lo mu oti kan amulowo
Oti ola la o mu o
Oti ti mo mu ti mo fi laje
Opelope Aranisan
Oti i re amu rire o
Oti ti mo mu ti mo fi laya
Opelope Aranisan
Oti i re amu rire o
Oti ti mo mu ti mo fi bimo
Opelope Aranisan
Oti i re amu rire o
Oti ti mo mu ti mo fi Nire Gbogbo
Opelope Aranisan
Oti i re amu rire o

SEGUIMOS CRECIENDO!

*ÌJÓ ÈGBÉ ÒTÚÁ RÉTÈ MODÚPÉ'OLA*

Potrebbero piacerti anche