Sei sulla pagina 1di 29

CHRISLAND SCHOOLS LAGOS

LITERACY LESSON PLAN

UNIT : CCI
SUBJECT : YORUBA LANGUAGE
TERM : SECOND
WEEK : 1
CLASS: YEAR 8 AND YEAR 10
EDUCATOR : ADESOKAN A.K.

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 11/01/2019 CLASS : Year 8 DATE : 9/01/2019 DURATION : OGORIN ISEJU
SUBJECT : Yoruba TEXT RANGE : Oju ewe 33-36

LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le :


INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Salaye nnkan ti a n pe ni isodoruko.
ii. Salaye orisii ona ti a n gba seda oro-oruko .
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iseda oro-oruko Oluko yoo beere ibeere Awon akekoo Oluko ati akekoo ni yoo jo Aworan lori i. Ki ni iseda Ko apeere oro-
lowo awon akekoo nipa yoo dahun maa daruko apeere si orisii kadiboodu oro-oruko? oruko mewaa ti
imo ateyinwa won lori ise ibeere oluko ona ti a n gba seda oro- ati ero ii. Daruko ona a seda ati bi a se
saa to koja. lori imo oruko. komputa. meta ti a le gba sedaa won.
Yoo bere idanilekoo lori ateyinwa won seda oro-oruko
iseda oro-oruko. lori awon ise iii. Daruko oro-
ti a se ni saa oruko meji ti a
to koja. ko le seda.

TUES Iseda oro-oruko ni ona ti a Won yoo fi


n gba seda oro- ara bale teti
oruko. Kii se gbogbo si alaye oluko
oro –oruko ni a le lori koko
seda. tuntun.
i. Oro-oruko aseda ni awon Won yoo se
oro-oruko ti a le afikun ohun ti
seda. Apeere : Ade, won mo lori
Ife, Iwosan, Alaso, ona ti a n gba
Atije abbl. se isodoruko.
ii. Oro-oruko aiseda ni
awon oro-oruko ti a
ko le seda. Apeere :
Igi, Eye, Oju, Apa,
Omi, abbl.
Awon ona ti a le gba seda
oro-oruko ni :
i. Lilo afomo ibere : a, i, o,
on, oni, ati, abbl.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK

Ona ti a n gba seda oro- Won yoo


oruko : beere ibeere
i. Lilo afomo ibere lowo oluko.
Won yoo
THUR ii. Lilo afomo aarin
dahun
iii. Sise apetunpe oro- ibeere oluko
oruko ni opin eto
iv. Sise apetun pe apola eko.
Ise.
v. Sise akanpo oro-oruko.
Yoo fun awon akekoo ni
aye lati beere ibeere.
FRI Yoo beere ibeere lowo
awon akekoo lati kadii eto
idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 11/01/2019
CLASS : Year 10 DATE : 7/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : Yoruba TEXT RANGE : Oju ewe 18-21
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le :
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Ko oro ni akoto ede Yoruba.
ii. Se amulo ofin ati ote ti o ro mo akoto ede Yoruba.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Atunyewo akoto ede Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Ero i. Tun awon Tun awon oro
Yoruba imo ateyinwa won lori ise dahun ibeere jo kopa pataki nipa kiko komputa ti oro wonyi wonyi ko ni
saa to koja. oluko lori imo awon oro ti atunse ti ba a ti ko ko ni ilana ilana ode oni :
Yoo fun awon akekoo ni ateyinwa won jade pelu opolopo apeere. apeere ode oni : i. Wipe
aago orisiirisii lati pe. lori ilana ati awon oro a. Peipeiye ii. Gegebi
ofin ti o ro atijo ati ode b. Oshodi
mo akoto. oni si ori re. iii. Biotilejepe
c. Osogbo iv. Offa
d. Olopaa v. Iddo
e. anu

TUES Àkọ́tọ́ ni sípẹ́lì tuntun tí Won yoo maa


àwọn onímọ̀ èdè pe awon ti o
Yorùbá fi ẹnu kò lé wa ni oju
lórí ní ọdún 1974 láti patako ni eyo
máa lò. Bí àpẹẹrẹ – kookan. Won
• Sípẹ́lì àtijọ́ yoo maa se
• Aiye atunse ti o to
si okookan.
• Eiye

• Gan an Yoo fi ara


• Èwoni bale teti si
• Gẹgẹbi alaye oluko
lori akoto.
• Sípẹ́lì tuntun
Won yoo se
Aye
afikun ohun ti
Ẹye won mo lori
Gan-an akoto.
Ewo ni
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK

Won yoo
Ẹniti Eni ti
beere ibeere
Shọla Ṣọlá
lowo oluko.
Nitorina Nítorí náà
Won yoo
THUR Nigbagbogbo Nígbà
dahun
gbogbo
ibeere oluko
ni opin eto
eko.

Yoo fun awon akekoo ni aye


lati beere ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
FRI awon akekoo lati kadii eto
idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 18/01/2019 CLASS : Year 10 DATE : 14/01/19 DURATION : Ogorin iseju

Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le :


i. DarukoSUBJECT TEXT RANGE : Oju ewe
orisii aroko ti o wa ninu ede Yoruba. 17-19
ii. Daruko awon ilana/igbese ti gbodo tele ki a to le ko aroko to gun rege..
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK

• LEARNING
MON Aroko kiko Oluko yoo beere ibeere Awon akekoo Atoluko ati akekoo ni won Apeere i. Igbese akoko Ko aroko ti ko
(asariyanjiyan) lowo awon akekoo nipa yoo dahun jo kopa pataki nipa aroko ninu aroko din ni Igba oro
imo ateyinwa won lori oge ibeere oluko didaruko apeere aroko asariiyanjiya ni …. lori : Omobinrin
sise. lori imo asariyanjiyan ati kiko ilapa n lori ero ii. Igbese to wulo ninu ile

• INTENTIONS (OBJECTIVES )
Yoo bere alaye lori ona ti a ateyinwa ero fun ori kan. komputa. gbeyin fun obi ju
n gba ko aroko to gun rege. won. ninu aroko omokunrin lo.
kiko ni…..

TUES • Awon koko ti a ni lati Won yoo fi


kiyesi ti a ba n ko ara bale teti iii. ……… ni o
aroko ni si alaye oluko maa n je ki
• 1.Koko oro [topic] lori koko aroko wa ni eto
• 2.Ilapa ero tuntun. to gun rege.
[guidelines] Won yoo se iv. Aroko gbodo
• 3.Eto koko afikun ohun ti ni ……………
[arrangement won mo lori
aroko
asariyanjiyan
• 4. Ifaara .
[Introduction]
• 5. Ede [language]
• 6. Ikadii [conclusion]
Aroko asariyanjiyan ni
aroko ti o maa n
sotun sosi. Iha meji
ni aroko yii maa n ni.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK

Apeere aroko asariyanjiyan Won yoo


i. Omobinrin wulo fun obi beere ibeere
ju omokunrin lo.
lowo oluko.
ii. Ise dokita wulo ni awujo
Won yoo
THUR ju ise agbe lo.
iii. Asiko ojo dara ju asiko dahun
erun lo. ibeere oluko
iv. Ile eko aladani dara ju ni opin eto
ile eko ijoba lo. eko.

Yoo fun awon akekoo


ni aye lati beere
ibeere.
FRI Yoo beere ibeere ni
owo awon akekoo lati
kadii eto idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 18/01/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 14/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 133-137
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Seda oro-oruko nipa sise apetunpe.
ii. Se afihan oro-oruko ti a seda ninu gbolohun.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iseda oro-oruko. •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Apeere oro- i. Ona Bawo ni a se
imo ateyinwa won lori dahun ibeere jo kopa pataki nipa siso oruko ti a meloo ni a seda awon oro-
isodoruko. oluko lori imo apeere ti o ba ona seda lori le gba lati oruko wonyi :
ateyinwa won isodoruko kookan mu.. ero fi seda i. Omoomo
lori iseda oro- komputa. oro- ii. Omokomo
oruko. oruko?
iii. Odaran
ii. Daruko
apeere iv. Owoori
meji fun v. Pejapeja
okookan.
TUES i. Lilo afomo ibere : Won yoo ka
I + fe = Ife akaye ni eyo
A + de = Ade kookan.
Ai + sun= aisun Won yoo
dahun
On + woran=onworan ibeeere ti o
Ati + je = atije tele akaye.
O + sise = osise
Oni + aso = Alaso

• Lilo afomo aarin :


Omo + ki + omo=omokomo
Ile + ki + ile = ilekile
Ije + ku + ije = ijekuje
Irin + ku + irin = irinkurin
Opo + ni + opo =opolopo
Owo + de + owo=owodowo
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
Sise apetunpe oro-oruko :
beere
i. Omo + omo = Omoomo ibeere lowo
ii.Odun + Odun = Odoodun oluko.
THUR iii. Iya + iya = Iyaaya Won yoo
Iv. Osu + osu = Osoosu dahun
ibeere oluko
V. Agba + Agba = Agbaagba
ni opin eto
eko.
Yoo fun awon akekoo ni
aye lati beere
ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
FRI awon akekoo lati
kadii eto idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 25/01/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 21/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 82-85
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES )
i.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Itan isedale agbala •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Ikarahun i. Awon wo ni Ya aworan
aye. imo ateyinwa won lori ise ti dahun ibeere jo kopa pataki nipa siso itan igbin, won gba awon nnkan
a se koja. oluko lori imo ti o jora won nipa itan iyepe,ekuro gbo pe wonyi :
Won yoo bere ise lori koko ateyinwa isedale agbala aye. ,boolu ohun nla i. Ikarahun
tuntun ‘Itan isedale agbal won. agbala aye, kan ti o igbin
aye’. bibeli. gbona ni ii. Ekuro
o jabo lati
orun ti a fi iii. Boolu
da aye? iv. Adie

TUES AWON ITAN METEETA Won fi ara ii. Awon wo ni


i. ITAN AWON YORUBA bale teti si won gba gbo pe
ii. ITAN AWON JUU (JEWS) alaye oluko nipase oro enu
iii. ITAN AWON ONISAYENSI lori ‘itan ni a fi da aye?
Awon Yoruba gba wi pe isedale iii. Awon wo ni
agbala aye’. won gba gbo pe
omi ni o wa lori ile aye.
iyepe ati adie ni
Olodumare fun orunmila ni
o se okunfa
ikarahun igbin ti erupe wa iseda aye?
ninu re, o si tun fun ni adiye
Awon onika merin,peekuro.
juu gbagbo juujuu
ni ile aye wa. Sugbon
Olodumare pase pe ki
imole ki o wa. Imole si wa.
Olorun fi oro enu da ile aye
ati gbogbo nnkan ti o wa
ninu aye. Oluwa olorun si fi
erupe mo eniyan o si fi
eemi iye sinu re.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
Awon onimo sayensi gba
beere
pe ohun nnla kan roboto bii ibeere lowo
boolu ti o gbona janjan ni o oluko.
THUR jabo lati orun to bu gbamu, Won yoo
ti o si fonka leyin ti afefe fe dahun
ibeere oluko
sii, o tutu. Gbogbo ibi ti o
ni opin eto
fonka de di eko.
ile
Yoogbigbe.
fun awon akekoo ni
aye lati beere
ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
FRI awon akekoo lati
kadii eto idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 25/01/2019
CLASS : YEAR 10 DATE : 21/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 24-27
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Salaye bi a se n ki eniyan ni asiko kookan ni ile Yoruba.
ii. salaye ikini ti o je mo ayeye kookan.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Ikini ni ile Yoruba. •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Aworan i. Ipo wo ni Ba wo ni a se n
imo ateyinwa lori bi a se se dahun ibeere yoo jo kopa pataki nipa sise ikini omobinrin ti ki awon wonyi :
ikni ni ile Yoruba. oluko lori imo afihan bi a se n se ikini ni omobinrin maa n ki i. Oba
ateyinwa won awujo Yoruba ati apejuwe ati
agbalagba ni ile ii. Babalawo
lori bi a se n ikini nibi ayeye lorisirisi. omokunrin
ki eniyan ni pelu orisirisi Yoruba? iii. Alagbede
orisirisi ayeye. ii. Bawo ni a se iv. Onidiri
akoko. n ki eniyan ni v. Agbe
owuro?

TUES 1. Ikini Ojumo Idahun Won fara iii. Ba wo ni a se


Aaro - E kaaro o Oooo bale teti si n ki eni ti o n
Osan - E kaasan o Oooo alaye oluko taja?
lori ikini. iv. Awon wo ni a
Ale - E kaale o Oooo
n ki ni ‘Aroko
2. Ikini nibi ayeye bodunde ooo’.
Igbeyawo - Eyin iyawo ko
ni meni o Ase ooo
Isinku - E ku aseyinde / E
ku ara fera ku.
Asea tura o Ase
Isile - Ile
Isomoloruko - E ku ewu
omo/ E ku owo lomi. - ooo
Iwuye - Oye a mori o Ase
3. Ikini lenu ise:
Ifa dida - Aboru aboye
Aboye bosise o
Akope - Igba a ro o
E se o/ ooo
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
Irun didi - Oju gbooro o
beere
Ooya a ya
ibeere lowo
Aro dida - Aredu o
oluko.
Iyamopo a gbe
THUR Agbe - Aroko bodun de o
Won yoo
dahun
Ase o
ibeere oluko
Awako - Awaye o / Oko a
ni opin eto
refo Ase o
eko.
Yoo fun awon akekoo ni
aye lati beere
ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
FRI awon akekoo lati
kadii eto idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 1/01/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 28/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 13-17
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Ka iwe ni akaye ati akagbadun.
ii. Dahun awon ibeere ti o ba tele akaye.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Akaye i. yoo beere ibeere lori
Oluko Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Akojopo O se pataki fun Ka akaye inu
imo ateyinwa won lori ilana dahun ibeere jo kopa pataki nipa kika iwe ibeere akekoo lati se idanwo odun
akaye
• ati didahun ibeere. oluko lori imo akaye ati didahun awon fun idanwo ………….. akaye. 2017, ki o si
ateyinwa won ibeere ti o te le e. NECO. Ti awon idahun dahun awon
lori ilana ati ba jora, ki ni ibeere ti o tele
ofin ti o ro akekoo gbodo akaye naa.
mo akaye. se ki o to mu
lo. idahun si ibeere
re?

TUES Yoo fun awon akekoo ni Won yoo ka


akaye lati ka . akaye ni eyo
Yoo salaye awon oro to kookan.
takoko ninu akaye ti a ka. Won yoo
Yoo se atunse lori idahun dahun
awon akekoo si akaye . ibeeere ti o
tele akaye.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 1/01/2019
CLASS : YEAR 10 DATE : 28/01/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 1-7
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Ka iwe ni akaye ati akagbadun.
ii. Salaye awon koko to jeya nibi ti a ka.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iwe kika •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Iwe asayan Salaye ipa ti Ko ni soki ohun
imo ateyinwa won lori. dahun ibeere yoo jo kopa pataki nipa (Iya Atata) okookan awon ti a ka ni ori kin-
Yoo beere alaye lori awon oluko lori imo kika iwe naa ni ipinro kan si akopa ti a menu in-ni iwe yii.
akopa inu iwe naa ni ateyinwa won ekeji.
lori ikini. ba ko nibi ti a
okookan.
ka.

TUES Won yoo ka iwe naa ni eyo Won yoo fi


kookan pelu alaye ara bale teti
lori ibi ti a ka. si alaye oluko
Won yoo salaye ipa ti lori koko
okookan akopa n ko tuntun.
bi itan se n lo. Won yoo se
afikun ohun ti
won mo lori
awon oro to
ba takoko.
.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 8/02/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 4/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 14-17
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Daruko orisii leta meji to wa pelu apeere.
ii. Ko leta to gun rege si obi tabi eni ti o wq nipo ase.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Aroko kiko •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Apeere leta i. Orisii leta Ko leta si oi re,
imo ateyinwa won lori dahun ibeere yoo jo kopa pataki nipa ni orisiirisii meloo ni o ki o salaya awon
aroko kiko (leta kiko). oluko lori imo sisalaye orisii leta meji to ni ori ero wa ninu nnkan ti o nilo
ateyinwa won wa ninu ede Yoruba ati komputa. ede ni ile-eko.
lori aroko awon apeere ti o ba Yoruba?
kiko. okookan mu. ii. Apa ibo ni
adiresi
akoleta
maa n wa?

TUES Orisii leta meji ni o wa ninu Won yoo fi iii. Iru leta wo ni
ede Yoruba. ara bale teti a kii da apara
i. Leta gbefe si alaye oluko ninu re?
ii. Leta aigbagbefe lori leta kiko
ati ilana fun
Leta gbefe ni leta ti a maa n okookan
ko si obi, ore, egbon, won.
aburo, ara, ojulumo.

Leta aigbagbefe ni leta ti a


ko si oga ile-eko, ile-
ise aiwe iroyin, leta
iwase, leta si alaga
ijoba ibile, leta si oga
ile ise.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 8/02/2019
CLASS : YEAR 10 DATE : 4/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 7-10
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Fun iro konsonanti ni oriki.
ii. Se apejuweniro konsonanti pelu abuda to ye.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iro konsonanti •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Ate iro .i. Ki ni iro Ya ate iro
imo ateyinwa won lori iro dahun ibeere jo kopa pataki nipa siso konsonanti konsonanti? konsonanti.
konsonanti. oluko lori imo awon abuda iro ti o fi ibi ati ii. Meloo ni
ateyinwa won konsonanti. ona isenupe awon iro
lori iro han. konsonant
konsonanti. i ti o wa
ninu
alifabeeti
ede
Yoruba?
TUES Iro konsonanti ni a pe,nigba .Won yoo fi iii. Awon abuda
ti idiwo wa fun eemi ara bale teti wo ni a fi maa n
ifo lati jade lasiko si alaye oluko se apejuwe iro
pipe re.(Consonants lori iro konsonanti?
are sounds made konsonanti.
with a degree of
obstruction to the
airflow

Mejidinlogun ni awon iro


konsonanti ede
yoruba. Awon
niwonyi ni ibamu
pelu ilana foonu:
[ b] [ d ] [ f ] [ g ] [ gb ] [ h ]
[j ] [ k ] [ l ] [ m ]
[n][p][r][s][s][t][
w][y]
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 15/02/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 11/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 13-14
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) 1. Fun iro faweli ni oriki ti o kun.
2. Se apejuwe iro konsonanti bi o ti ye.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iro faweli ede •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Ate iro i. Ki ni iro Ya ate iro iro
Yoruba. imo ateyinwa won lori iro dahun ibeere jo kopa pataki nipa sise faweli. faweli? faweli
faweli. oluko lori imo apejuwe iro faweli ni eyo ii. Meloo ni aranmupe.
ateyinwa won kookan. awon iro
lori iro faweli. faweli ti o
wa ninu
alifabeti
ede
Yoruba?

TUES Faweli ni iro ti a pe laisi Won fi ara iv. Orisii faweli


idiwo fun eemi amisode/ bale teti si meloo ni o wa?
eemi edo fofo. alaye oluko v. Ipo meji wo ni
lori iro faweli. ete maa n wa ti
Orisii faweli meji lo wa :
a ba n pe iro
Faweli aranmupe ati faweli faweli?
airanmupe. Faweli
airanmupe ni a, e, e, i, o, o,
u. awon faweli airanmupe

yii je meje nigba ti awon


aranmupe je marun-un Ona
meta pataki ni ahon ti lee
gbera ninu enu, awon ni
iwaju ahon, aarin ahon, ati
eyin ahon. Awon faweli ti a
pe pelu iwaju ahon ni a mo
si faweli iwaju, nigbati
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
awon ti a pe pelu aarin Won yoo
ahon ni a pe ni faweli aarin, beere
awon ti pe pelu eyin ahon ibeere lowo
ni a n pe ni faweli eyin. oluko.
THUR Awon faweli ti o je faweli Won yoo
iwaju ni I, e, e, in, en. dahun
Awon faweli aarin ni a, an. ibeere oluko
Awon faweli eyin ni o, o, u, ni opin eto
on, u. eko.
Yoo fun awon akekoo ni
aye lati beere
ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
FRI awon akekoo lati
kadii eto idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 15/02/2019
CLASS : YEAR 10 DATE : 11/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 122-124
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Salye ona ti a le gba ran ara eni lowo.
ii. Salaye iwulo ati aleebu okookan won.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Asa iranra-eni-lowo. •
Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Aworan. lori i. Ki ni ona i. Ki ni iyato to
imo ateyinwa won lori ise ti dahun ibeere jo kopa pataki nipa ero iranra-eni lowo? wa laarin owe
a se koja lori iro oluko lori imo didaruko awon ona ti won komputa. ii. Daruko ona ati aaro?
konsonanti. ateyinwa lori n lo lati ran ara won lowo ni meta ti a
ise ti a se aye atijo. le gba ran
koja. ara wa
lowo.

TUES Awon Yoruba gba pe ajeje Won yoo fi


owo kan ko gberu dori, ara bale teti
won si gba pe ika ko si alaye oluko
lori koko
dogba,idi niyi ti won fi maa tuntun.
n ran ara won lowo.
ORISI ONA IRANRA-ENI-
LOWO NI AYE ATIJO
1.AARO: Ona yii ni awon
baba nla wa fi n se ise oko.
lona tioklona
ko fi nitika
fi ni
wonpa laya.
won
laya.
Awon ti won ba ko ara won
jo fun aaro gbodo je
i. Awon ti agbara won
dogba.
(ii)Awon ti won ni oko si
itosi ara won.
(iii) Awon ti won ni oko ti o
po, ti o gba aaro ti.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
Dandan ni sisan aaro pada.
beere
Pipese jije ati mimu ko pon
ibeere lowo
dandan.
oluko.
Won le maa fi orin ati
THUR apara okan ko jokan da ara
Won yoo
dahun
won laraya bi ise ti n lo.
ibeere oluko
2.OWE: A le be owe fun ise
ni opin eto
oko, ile kiko ati beebee lo.
eko.
Yoo fun awon akekoo ni
aye lati beere ibeere.
Yoo beere ibeere ni owo
awon akekoo lati kadii eto
FRI idanilekoo.

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 29/02/2019
CLASS : YEAR 8 DATE : 25/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 28-30
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le ;
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Ka onka ede Yoruba lati ookan de ogorun-un.
ii. Tele ofin le ati din ninu onka won.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Onka ni ede Yoruba. Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Koro i.Ori onka Ko awon nomba
imo ateyinwa won lori iro dahun ibeere jo kopa pa ninu kika awon agbalumo, wo ni le ti maa wonyi :

faweli. oluko lori imo nomba ni eyo kookan . igi isana, n pari? i. 76
Yoo bere idanilekoo lori ateyinwa won okuta wewe ii. 88
lori iseda oro- abbl. ii. Ori onka wo
koko tuntun. iii. 102
oruko. ni a ti maa n
bere din? iv. 134
iii. Awon nomba v. 141
wo ni a maa n lo
aado fun?
TUES Onka ni kika iye, ipo. A maa Won yoo ka
n se onka , ohun ti o lemii akaye ni eyo
ati eyi ti ko lemii . A maa n kookan.
lo le (+) fun afikun lati Won yoo
dahun
ookan titi de eerin (1-4) ibeeere ti o
ninu onka Yoruba, nigba ti tele akaye.
a maa n lo din(-) fun
ayokuro lati aarun titi de
.
eesan-an (5-9) ninu onka.
Le = + (1-4)
Din = - (5-9)
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLAN
WEEK ENDING : 29/02/2019
CLASS : YEAR 10 DATE : 25/02/2019 DURATION : Ogorin iseju
SUBJECT : YORUBA TEXT RANGE : Oju ewe 133-137
LEARNING Erongba : Leyin idanilekoo, akekoo kookan yoo le :
INTENTIONS (OBJECTIVES ) i. Ka iwe ni akaye ati akagbadun.
ii. Salaye awon koko to jeya nibi ti a ka.
WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITIES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
MON Iwe kika. Oluko yoo beere ibeere lori Won yoo Atoluko ati akekoo ni won Iwe asayan. Salaye ni soki Ko ni soki ohun
• ateyinwa won lori iasa
imo dahun ibeere jo kopa pataki nipa sisalaye eko ti a ri ko ibi ti a ka ni ori kin-
iranra-eni-lowo. oluko lori imo awon koko to jeyo nibi ti a ti a ka. in-ni iwe yii.
ateyinwa won ka...
lori asa
iranra-eni-
lowo.

TUES Won yoo ka iwe naa ni eyo Won yoo ka


kookan pelu alaye akaye ni eyo
lori ibi ti a ka. kookan.
Won yoo salaye ipa ti Won yoo
okookan akopa n ko dahun
bi itan se n lo. ibeeere ti o
tele akaye.
CHRISLAND SCHOOLS LAGOS
LITERACY LESSON PLANS
WEEK ENDING:
CLASS: DATE: DURATION :
SUBJECT : TEXT RANGE :

LEARNING
INTENTIONS:
(OBJECTIVES)

WHOLE CLASS TEXT GUIDE GROUP ACTIVITIES ACTIVITES WHOLE CLASS PLENARY RESOURCES EVALUATION HOMEWORK
Won yoo
beere
Yoo fun awon akekoo ni ibeere lowo
aye lati beere ibeere. oluko.
THUR Yoo beere ibeere ni owo Won yoo
awon akekoo lati kadii eto dahun
idanilekoo. ibeere oluko
ni opin eto
eko.

FRI

Teacher's Name: ADESOKAN A.K.


(If you need to reproduce notes, please do so on the next page )
Supervisor’s : Comment :
Supervisor’s Signature & Date :

HOME

Potrebbero piacerti anche