Documenti di Didattica
Documenti di Professioni
Documenti di Cultura
Okete aaye kan, eku asin oniyo 9 fun okunrin, 7 fun obinrin, odindin atare kan, egbo tude idi mesan
fun okunrin, idi meje fun obinrin, ape tuntun.
SISE RE
ao pa okete yi ti eje koni jade lara re, ao wa la idi re die, ao ki gbogbo asin yen sinu re, ao fi atare di nidi, ao
gbe sinu ape , ao ko egbe tude bo lori . O di jijo.
ti a ba ti jo tan, ao lo kuna daada, ao wa ro sinu nkan toba wuwa.
LILO RE
ao ma fi hot loo lararo ni deede ago mefa idaji.
Hmmmm....., eyin eniyan mi, nigbati mo koko gba ise yi lodo baba to fun mi, mio kaa kun oogun, sugbon
nigbati mo danwo, mo sese wa gba wipe oogun tiije di ola ni.
nigbati mo se , mo ri owo daada sugbon mio fi ra motor nigba yen.
o wa ku si owo eyin eniyan mi, ti e ba ti bere sii loo, gbogbo owo ti e nba ri , e ma toju re ki e le fi ra motor
niooo. mo si mo wipe owo motor yin yio pe pere pere !!!
3 Ebe asina
Ewe bomubomu meje fun obinrin mesan fun okunrin a o gun pelu ori ati eepo obo a o wa po mo ose
dudu a o we ni alaale fun ojo meje tele ra won,
E gbiyanju re wo confirm ni, ki eledumare fi ase si gbogbo igbiyanju WA, ki olohun ba mi so oga mi
pada layo ati alaafia, ifadire akinade iba ni mo se o, iba oonirisa, ologbenla ayamoparakogi iba re o.
Iba re omo adepoju apesin ola 1
5 (1) AWÒRÒ
Owo eyo tikoluju 21, Ota inu iroko, Iyo oni kobo kan, idi kan (#20) Èyin Adie meta 3, Aojo Èyin yen
sibikan Aolo korofo Èyin na mò Awon Nkan Yoku Aowa Dasinu Èyin ti ajoyen Aoro sinu Sèrè kan
aowa di lenu pèlu Owo Dudu ati Funfun ni aofidi lenu oo idi sere ti kogbudo kanlè mò
Aogbe ko ibi ti angbe nta oja.
(2) AWÓRÓ
Epo òbò eepè Enu ona, Eyo Atare 21 aolopo aoda agbon kanlu ni ibi oju meteta aoda omi inu rè danu aoro
ogun yisi ao ro adisi aosoko senu onawa..
(3) AWÒRÒ
Agolo ere funfun1 (white beans) Agolo agbado funfun1 Agolo oka baba funfun 1, aoda meteta pò sinu igba
olomori aotu igo epo kansi tan patapata aogbele nibi ti ati nta oja tabi Enu Ona office wa aowa gbe igba yen
sinurè aowa mu eiyele funfun kan lowo aosope ire ti IWO eyele yiba kowole mako jade mò oo atotun atosi
leyele fikore wole, Okunrin, Obinrin, omode Agba kiwon ma towowon wa oo..
N.b aoti koko fi toju eiyele yen ninu aye ibi ti aferimo fun ojo meje ooo.
7 AWENU ATUDE
OTA inu iroko.
Epo obo
Egbo tude.
Ao lo won papo. Ti yoo kuna daadaa. A o fi the osa meji...a o dadura atude si. ...
Iba olorun3x , iba eyin iya mi aye, afinju eye ti n fo loganjo our, iba eyin olake opake alagogo ide. Eyin ologbo
dudu eti aja, ti I damo ni dagiri loju orun , eyin aja dudu aboju merindinlogun, e wa tu gbogbo ide ara emi
lagbaja omo lagbaja. Ide airije, ide aitegbe, ide airowo saye, lati eni lo kin bosola, kin no sowo...
A o tun fi te ejiogbe. A o sadura si...
Ela ro3x
IFA ro wa...
IFA to ba roko ki o de, to ba rodo ki o bo, to ba n be loke geti ko wa tu gbogbo ide aye emi lagbaja omo
lagbaja...ejiogbe wa GBE ide aburu kuro ninu aye mi.....
. A o wa daa sinu ike olomori kan a o maa bu die somi gbona fi Sanra sun fun ale mesan
10 ATUDE AWENU.
E Ku iwaju o, gbogbo eyin ojogbon ti e nda si eto ironlowo EDA ninu ile yi o, yio maa juse fun waa o.
E je ki a se agbo kekere yi si ile ki a maa we ni igba kugba.
Ao was eepo obo lopolopo, ao pa pe pe pe, ao ko si ike oda nla, ao fi omi re, ao da iyo ekun wo meji si, ao gbe
pamo si inu ile, leyin ojo keta ki a maa bu we, tabi fun a won onibara wa.
Bi a ba ti bu bi abo nla meji is inu garawa iwe, o ti to, ao fi omi laa.
Ao maa fi omi tuntun ropo eyi ti a bu, ao si run maa bu iyo pada si ni orekore
15 OSE AJEGUN
Ise yi dara pupo fun eniti owowa larare ti ogun kitete sise larare tabi ti ogun koje larare rara gbiyanju
koni oseyi ninu ile papa awati anda alejo loun
Ifun Ako alangba kan
Ata ijosi wewe
Aogun papo aopo lose dudu aomafi ose fowo koju beelo,
16 EBE AWON AGBA *** Ako alangba kan, eku asin meta, epo obo, ao gun po,
ao po lose, ao kosinu ike ff, ao fi ikode kan gun Lori, Ale ni wiwe ose yi, ti abatiwe tan, ti Omi tigbe
lara wa, ao wa yo ikode ori ose yen, ao fi nu arawa Wale, ao tun fi gun ose yen lori pada, bi
aosemalo niyen.
17 OSHO-ASINA
Ori aja tiwon befun ogun, ao ki kowe kan bo lenu, ao gbe sinu agbada, ao fi tako-tabo alangba tutu
si pelu Odd atare kan. Ao wa ko opolopo egbo tude le lori. Ao wa fi awo-etu niwonba bo loke. Odi
jijo...... Ao lo kuna dada, ao ro sinu igo ff, ao kan eyo igbale kekeke meta, ao ju sinu ise yi, ao gbe
pamon sugbon idi re o gbudo kanle. Ao mafi fokomun ni 12:00am.
19 Atude asina tabi igba eyan ti aisan nse sile lowo awon mummy
Ao koko se etutu yi nan.
Ao pa ewure dudu kan ao mu ifun edo ati okan re sinu igba nla tabi awo sobi to tobi dada pelu epo
pupa.
Ebu re :
Ao jo oori igun pelu ewe jin ati atare to gbajumo kan. Ao lo kunna ao bu die ninu ebu yi sori ipese yi.
Ao se iya nla adura si ki alaisan leri iwosan.
Ao lo gbe sori orita meta ni ihoho omoluabi ki ama ba ka abama lati gbe Eran won tabi ki awon ebi
wa tabi ebi awon tongbe alaisan wa sodo wa ma le ka abama re.
Leyi ti ase ipese yi tan ao wa jo awon eroja yi:
Eku asin kan
Opolo ijokun aye tabi gbigbe kan
Oga gbigbe kan
Ewe ajeobale
Epo obo
Ata ijosin die. Ao lo kuna dada ao fi sin gbere si orikerike ara alaisan nan. Ao Tun fi die ninu ebu yin
fi po ose ti yi OMA fi We lorekore.
Iba eyin toni aye ooo
20 OGUN AGBA DIDA TE YAN FI NPE KARIN KESE.
Iroko to sese hu soke, a o gbedi re, a o fatu, a o se obi ifin si oju iroko ti a tu na, a o kile mo, a o lo
iroko na tewe tegbo re, a o feje adie funfun lo pelu atare ati oku imi osumare, a o sin ni gbere 200
sori, ti a ba feku, a o fo eyin adie sori.
24 ISORI TODAJU
Adan iyekiye
Orogbo lopolopo
Opolopo atare
Ota inu iroko
Aofe epo atare yen danu aogun gbogbo awon nkan yen papo ti yio kunna bi paoda. Aofi ebuyen te odu ifa
okanran iyeku
Ofore- ogbagbamogbe. Odudua keji. Olojo landajofun katoledide. Ogbagbamogbe ni oruko ti anpe iku.
Odudua keji ni oruko ti anpe arun. Olojo landajofun katoledide ni oruko ti anpe awon iyami aje. Awon ni won
parapo tiwon se ifa fun orunmila nigbati omo araye ro tikutiku. ti wonro taruntarun. Orunmila ajano oni iku
koni ohunpa. Oni arun koni ohunse. Won ni kilogbojule tofisobe. Orunmila ni ohun gbojule ota iroko. Won ni
se ota ni iroko ngbojule ti iku kifipa rewerewe. Orunmila ni beeni. Oni ojojumo tiwon bape orogbo magbo
sowo somo Si alafia. Efun kiidi atare monu iyare komaleta edidi kiidi atare komaleta. Ti arabani ikansoso adan
IGba odide nigbakureku. Okanran oyeku ye ikumi le otami lori. Okanran oyeku ye aisan tiibasemi le otami lori
okanran oyeku, eko tutu laoma filo igbakigba ni lilore. Gbogbo awon ota tofe mabinu sie yen wonti oku
27 Fun Asaisi\ Abulu Oju Orun Ati Ki Awon Agba Male Yowa Lenu Loju Orun
Wa~egun Ori Atiba Die,ota Inu Iroko Die Aolo Po,ao Ma Koko Fin Si Imu Wa Ao Si Mafi Sari Lalale
Atosun,odaju Pupo,ejeki Eleye Na Mobo Wa Lati Seyin Ni Ibi,yio Ko Agbako Ni Odaju Pupo
29 AWENU BI ARA BADOTI = Ti idoti bawa lara re, matanrare o le rowo, koda
kose asiri Owo jubelo o, ojukan nani watimabarare.*** koro inu owu akese eyo mesan, eso
werenjeje mesan, epo obo die, epo asorin niwonba, ao lowon kuna loototo lori olo, ao sese wa
dawon po, ao ko won si idi-odo igunyan, idi odo yen latima pomo ose dd pelu omi idi igbin, ao pin
ose yen sona mesan, ao wa su ewe ejinrin ni kanhinkahin ni ona mesan, ao ko ose yi si leyo
kookan, ao ko gbogbo e, odi odo tonsan,ao eeru para kia to bere sini we, alakoko ti abati fi para yen
nani o, elekeji aofi nkankan para Mon titi aofiwe mesesan tan, bi abasen we ikokan tan, ao mafi
itakun ewe tobaseku lowo wa kale segbe kan ti ao fiwe tan, ti abawe tan, ao gbele si eti odo yen, ao
ju igbin ti a lo omi re yen sinu koto na, ao ko awon aloku kanhinkanhin ejinrin yen le lori, ao da yepe
bo monle. Ao pada Sile. Hmmm ikan niyen ninu AWENU TOYANJU.
33 TUDE .
Oro agogo ao ge kekeke, aodasinu ikoko agbo,adaripon tutu kan, eyin ibile kan, aose pelu omi toba
jina tan aoyo omire aofi omi totowe si
Ao gbe koto kan tio jin die ibe laotiwe agbo yio aowe agbo yi sibe leyin na aoje eyin yen ninu koto yi
ki ato jade nibe ti abawa jade tan aofo ikoko yi sinu koto yi aoro iyepe bo aofi kehinkehin nasi inure o
OSE RE.....aidan aoha igun re mererin aolo pelu eru alamo, alomu funfun pelu dudu aopmo ose dudu ohun
laofiwe agbo yi ....bi olohin bafun o se inshaallahu wadu folohun ninu igbesi aiye toku
36 EBU IPESE TIA FI MAUN BERE GBOGBO NKAN TIA BAFE LOWO AWON
AGBA"
"IPESE ELEYI KISE IPESE TIA MAUN GBELO SI ORITA, IWAJU ITA WANI AWON GRANDMA
TIMA WAJE NKAN WON""
ao wa Ibepe dudu kan, ao jo pelu odidi atate kan, ao lo ti yio kuna daada, ao wa ro sinu ado kan, ao
gbeko si igun ile, ao nije ki idi ado yan kan lemo
LILO RE, TIA BATI FELO
ao lora eran elede ti koni egun rara, ao gesi 16, aoko sinu awo ipese, ao wa bu ebu die, ninu ebu tia jo yan, ao
fite ifa osa meji, ao pe gbolohun re si, aniyan nkan tia fe, ao wada le ori Eran elede towa ninu Awo yan, ao bu
epo pupa le lori, ao logbe si iwaju ita wa...
GOLOHUN TI AO PESI RE
Eyin iyami osoronga, eyin ni afinju eye tinrin tolonge tolonge, eyin ni afinju eye abiye gbaramu gbaramu,eyin
ni afunwon ladie sin tiigba odidi eran lowo won, eyin ni afinju adaba tiun je Larin orofo, eyin lafinju eye tiun
je ni gbangba ile oba, emi lagbaja omo lagbaja nimo npeyin o, ewadami lohun lori nkan bayibayi, ao Se adua
nkan tia fesi, ao gbesi iwaju ita wa...ao lowo ni idaji kutu ni aro ojo keji, ti won bati gba ipese yi hmmmmmm
BUKATA na tibiya Kia ma reti esi ayo loku
40 ORUKA APASE/GBETUGBETU:
Ewe ina,ewe esinsin,ewe awaragba,egbo akerejupon,kankanti won fiwe fun oku,aogun won papo
mose,ao wa fi oruka irin meta senu oga aye,aowa le ose yen mo lara,ao fi ewe ogbo yi gbogbo arare
pelu,ao lori mole fun ojo meje,ao wu lojo keje aojo pelu odindi atare kan,aowa yo oruka yen sinu igo
kan,aomaa fiba enu bere nkan,ao la epo ti abase tan
41 ALUGO
Eso bara,oruka elelo merin,omm atare mesan. aopa bara yi ni pansa ao to oruka won yi si larin ti
won yio fi enu kan ra won ao wa ko omo atare mesan si larin ibiti won ti fenu kan kanra.ao fi omori re
de pada ao gbele tabi gbe idi aro ao gbe si ao dana le lo titi yio fijotan ao ko oruka wonyi odi lilo.lati
danwo efi saarin paper ki e gbe pamo yio je jade
43
OGUN FENIKU FOLADIDE{SICKLE CELL}
1:Ewe ose wewe,irawo ile ati orin ataa. Ao se lagbo fun mimu
2: Poporo okababa, ao ma re sinu omi fun mimu.
44 GBOLOHUN AFORIJI..
Ao hin omo atare mesan si enu pe ohun yi laro kutu:-
ijinji ti mo ji moji mo bade lori igun, won ni akii bade lori igun ki a pa igun, ojinji ti mo ji moba alugbara
lorun akala ki a pa akala, ijinji ti mo ji mo ji mo ba sekeseke lese odidere, won ni a kii ba sekeseke
lese odidere ki a pa odidere, ape fijin la pe oniru, a pe fijin la pe oniyo, a pe fijin la pe elepo, oso ile,
aje ile, lebo logun, alalufa, emere(ati bebelo). Ni mo ba se nile yi ki won fori jinmi ki won somi di
omo, won ni tori kinni moni tori mo ti jawe oriji mo ti wagbo oriji, oro mi di afi jin.Ao tu atare ti anje yi
siwaju lemeta.
26