Documenti di Didattica
Documenti di Professioni
Documenti di Cultura
ODI OGUNDA
(Odiogunda)
I I
I II
I II
II I
83 - 1
Orumila y idi-ogun-da
mo ni idi-ogun-da
orumila y bi idi ogun
ti dara yi kiowa rubo
ki ori re le dara pelu.
agutan eyele egbaa
mejielogun owo ati ewe ifa.
ogun gbo o ru
ori ogun dara.idi ogun dara.
orumila y idi ogun da,
mi idi ogun da.
a de le ogun a kob’enikan,
mo ni eetiri ile ogun tiakob enikan
gbogbo ile da kesekese,
won ni :iwa ogun ko sunwon,
nje biabiwipe
ki ile ogun kun somusomu
ebo ni kiase
ewure,egbaawa
owo aati ewe ifa.
83 - 2
83 - 3
´
Ifá pé kí eléyìun ó rúbo
kó lè baà' di eni òkánkán. ' '
' ' ' ' Ifá pé ó tí n rìn ìkòkò.
Ifá pé owó àti eyelé lebo.
Dinndinnkúdá
` ` Dìnndínnkúdá
A díá fún Dùndún
´ Tí tí n rìn ní kòkò
´ ' ' Tí tí n rìn ní bàábá
Wón ní kó rúbo kó le
' ' ' deni òkánkán gbangba
Wón ní òpòlopò eyelé lebo
' ' ' ' ' ' ' ' ' Òpòlopò owó lebo
' ' ' ' ' ' Awoo pálà lebo
'' ' ' Won è é tíí pé Dùndún télè rí
' ' ' Dùndún sà á n be ní kòrò
´ ' ' ' Ngbà ó rúbo tán
' Ó bá dojó kan
' ' Wón bá ní wón ó lòó pè é wá láti Ààfin
' ' ' ' Òun náà?
Ìgbà ó de òhún
' Dùndún té gbàjá aré sílè
' '
Gbogbo ihun tí àwon ìlù tó kù ò le se
' '
Dùndún bá se gbogbo è
' Wón' ní eni tí ó móo lù fún Oba jó láíláí nìyí o
' ' ´ '' ´ ' Ni Dùndún bá n jó ní n yò
'
Ni n yin àwon Dinndinnkúdá àti Dìnndínnkúdá
´ ` `
' ´ Àwon Babaláwo è n yin Ifá
' Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
'' ' Dinndinnkúdá
` ` Dìnndínnkúdá
A díá fún Dùndún
´ Tí tí n rìn ní kòkò
´ ' ' Tí tí n rìn ní bàábá
Wón ní kó rúbo kó le deni òkánkán gbangba
' ' ' ' Mo mòmò yin Dinndinnkúdá
' ' ` ` Mo yin Dìnndínnkúdá o
´ Dùndún tí tí n rìn ní kòkò
' Dùndún
' wáá deni òkánkán gbangba
' ' Mo yin Dinndinnkúdá
` ` Mo yin Dìnndínnkúdá o
Mo wáá deni òkánkán gbangba
' '
Ifá está pidiéndole a esta persona ofrecer
ofrezca sacrificio para llegar a ser notado
dentro de la sociedad. Ifá dice que él no
se ha reconocido previamente.
Él debe sacrificar palomas y dinero.
Dinndinnkúdá
Dìnndínnkúdá
Adivinación lanzada para el tambor Dùndún
Que nunca había sido notado
Eso nunca se había prestado alguna atención
Le pidieron que realizara sacrificio para llegar a reconocerse
Ellos le dijeron que sacrificara muchas palomas
Dinero suficiente
Y cualquier piel animal joven
Dùndún nunca había estado rezagándose
alrededor de las esquinas
Después él ofreció el sacrificio
Un día
Ellos enviaron para él del palacio del rey
'Yo'? Él exclamó cínicamente
Cuando él llegó allí
Él realizó extensivamente
Todo el golpe de tambor que
otros tambores no podrían lograr
Dùndún hizo todo
Ellos razonaron
que él debe ser el
que debe estar tamborileando
entonces adelante para el Rey
Dùndún el tambor empezó a
bailar y regocijar entonces
Él estaba alabando su Babaláwos,
el Dinndinnkúdá y Dìnndínnkúdá
Sus Babaláwos estaban alabando Ifá
Él dijo que era exactamente
como su Babaláwos predijo
Dinndinnkúdá
Dìnndínnkúdá
Adivinación lanzada para el tambor Dùndún
Que nunca había sido notado
Que nunca se había prestado alguna atención
Le pidieron que realizara sacrificio
para llegar a reconocerse
Yo lo alabo Dinndinnkúdá
Yo lo alabo Dìnndínnkúdá
El tambor Dùndún que había sido inadvertido alguna vez
Se ha vuelto el líder claro ahora
Yo lo alabo Dinndinnkúdá
Yo lo alabo Dìnndínnkúdá
Yo me vuelvo el líder claro ahora