Documenti di Didattica
Documenti di Professioni
Documenti di Cultura
Os materiais utilizados nos Ebos sempre serão obtidos em uma consulta ao Ifa..., menciono aqui
somente alguns ofos de ativação dos elementos mais usados no ritual:
AGUA (OMI)
__________ omi ni yi
Omi ni nmu aye toro
oun ni a nlo fun gbogbo nka laye
omi ko ni pa e lori
omi ko si ni gbe e lo
bi omi ba bale
omi a lepa wa lwpa owo , ola , omo
a ki nba omi sota
ki a bori
wa bori ota re o
omi ni npa ina
wa pana oke isoro aye
TRADUÇÃO
_________ epo ni yi
asodero ni
aye re yoo lero
wa ni oro sowo sayo ati si alafia
TRADUÇÃO
________oti ni yi
Otura lale mu
irete larera
Adifa fun Aranisan
Ti omu igba oti kan amu lowo lowo
Oti ola la o ma mu
TRADUÇÃO
OBI
_______obi ni iyi o
obi ni nbe iku
obi ni nbe arun
obi ni nbe ejo
oun naa ni nbe ota
a ba e be gbogbo ohun buruku ile aye
TRADUÇÃO
Nome da pessoa , aqui esta o Obi
E o obi quem aplaca a ira da morte ,
e ele quem aplaca a ira da doença
e o obi quem aplaca a intriga
e ele tbm que afasta inimigos e perseguições
ele afastara de você todo o mal existente no mundo
OROGBO
______orogbo re o
orogbo ni ngbo eni saye
wa gbo wa to la ye
ki o to lo si ibi tiagba nre
aye o ni se e ni abilu fun awo obi re
TRADUÇÃO
______atare re o
atare ki ndi tire labo
odindin ni atate ndi tire
o ko ni di tire labo
opolopo omo ni atare ni
wa lomo lopo
wa lowo lopo
wa ni alafia lopo
wa ni ohun gbogbo lopo
TRADUÇÃO
Nome da pessoa , aqui esta a pimenta pra você
ela não tras sementes pela metade
vem repleta de sementes
nada em sua vida será pela metade
a pimenta tem sempre muitas sementes
você terá muitos filhos
terá muita saúde
terá muito de tudo
como a pimenta tem muitas sementes
EJA (PEIXE)
______eja ni yi
ori ni eja fi nla bu
eja ni nboro omi
iwo o maa bori isoro iwaju re
TRADUÇÃO
OYIN (MEL)
______ oyin ni yi o
ki aye re dun titi bi oyin
dindun dindun ni a maa nba afara oyin
aye re yio maa dun
a ko ni ri oun ibaje ni ile aye re
TRADUÇÃO
Nome da pessoa , aqui esta o mel
para que sua vida seja eternamente docê
o favo de mel e sempre docê
não tera dificuldades insuperaveis
IREKE (AÇÚCAR)
_________ireke ni yi
ki are re ni adun
ki aye ni ayo
ki aye ni ola
TRADUÇÃO
IYO (SAL)
_______iyo ni yi
iyo ki nba nkan je
o ntun nkan se ni
o ni si nidi baje baje
iyo ki de inu ounje ki o ma dun
bi o ti se de si arin awon obi re yi
afekari aye ni a nfe iyo
teru tomo yoo fe o kari aye
TRADUÇÃO