Sei sulla pagina 1di 5

Iworika (1).

a.Ese ifa:
Ki won jo siwaju, ki won jo seyin a difa fun osun
aluki fun omo tuntun awon lo gbe ni isalu orun ni won
n bo ni aye won ni ki won rubo pe ibe a san awon lawon
difa si won ni ibe a san won pe ebo ni ki won ru oyin,
iyo, adun, gbogbo nkan enu ba nje, osun rubo omotuntun
naa rubo ti omo tuntun ba nbo nile aye niwon ma fi
osun pa lara bi omo tuntun se ni oluke, oluge niyi ni
ousn naa di eni aye fe tire naa, eni ti o da ifa yi ko
rubo pe adura re ma gba pe awon meji niwon jo nrin po
ki on le jo se ori re.
Words of ifa verse:
Ki won jo siwaju, ki won jo sehin, predicted ifa
divination for Osun and new baby two of them are from
heaven they are coming to earth they said they should
perform sacrifice that the earth will serve them well,
honey, salt, adun and all foods, two of them perform
sacrifice then the new baby now come to earth they now
used osun to rub new baby body this how new baby
become important to everyone, ifa said the person tht
divine iwori ayoka should perform sacrifice that the
person prayer will be answered and they are two friend
that they should perform sacrifice to make two of them
a successful in life.
b.Ikilo ifa
Ifa ni eni ti o difa yi ki o rubo pe adura re ma gba
ati wipe ore meji niwon ki won rubo ki awon mejeji le
sori re
Ifa instruction:
Ifa said the person that divine iwori ayoka should
perform sacrifice to make the person prayer to be
answer and they are two friend they should perform
sacrifice to make them succeed in life.
c.Nkan ebo:
Oyin, iyo adun, gbogbo nkan ti enu nje
Materials and animals:
Honey, salt, adun, all foods
d.Aladimu:
Ifa ni aladimu ti a o bo.

Offering:
The person will worship ifa.
e.Pipese nkan ebo
Babalawo yi o ba eni ti o difa yi bo awon ifa pelu oun
ebo ti won ti pese sile, yoo si wure fun lopolopo.
Method to prepare the medicine
The ifa priest will assist the client to perform
sacrifice to ifa and he give the person prayer.
Iworika (2).
a.Ese ifa:
Bi won ba da iwori ayoka ijo najo lode biwon-ba da
iwori ayoka esin naa fin bale, o difa fun olomi tutu
to se aya barapetu loja omo araye fi oju iku re da
piriti won ni ki o rubo ki o fi obi bo oke ponri oko
re lojo naa ni o se lo bo oke ponri oko re bi ku ko se
pa olomi turu ti se aya barapetu mo ni yi, eni da ifa
yi ko rubo ki iku ma se pa iyawo ati wipe ki o lo
teriba fun oko re naa, akuko 1, ayebo 2, eyele 1, eku
2, igbin a o fi ayebo1bo oke ori oko re ifa ni won pe
be o.
Words of ifa verse:
Bi won ba da iwori ayoka ijonajo kale, bi won ba da
iwori ayoka erin naa ri kael, predicted ifa divination
for cold water the wife of barapetu loja, human being
want to kill her they said cold water should perform
sacrifice with kolanut to worship ifa and after
sacrifice cold water did not die again, ifa said the
person that divine iwori ayoka should perform
sacrifice because untimely death not to snatch the
person wife or a woman should respect her husband very
well, 1 cork, she hen 1, pigeon 1, rat 2, fish 2,
snail, we are going to used the she hen to perform
sacrifice to ifa
b.Ikilo ifa:
Ifa ni eni ti o difa yi ki o rubo ki iku ma se pa
iyawo re tabi ki eni na lo teriba fun oko re.
Ifa instruction:
Ifa said the person that divine iwori Ayoka should
perform sacrifice to make the person not to loose his
wife with untimely death or a woman should respect her

husband very well.


c.Nkan ebo:
Akuko 1, ayebo 2, eyele 1, eko 2, eja 2, igbin 1.
Materials and animals:
1 cork, she hen 2, pigeon 1, rat 2, fish 2, snail 2.
d.Aladimu:
Ifa ni aladimu ti a o fi obi ati ayebo adie bo.
Offering:
The person will worship ifa with kolanut and 1 she hen
e.Pipese nkan ebo:
Babalawo yi o ba eni ti o difa yi bo ifa pelu oun ebo
ti won ti pese sile, yoo si wure fun lopolopo.
Method to prepare the medicine
The ifa priest will assist the client to perform
sacrifice to ifa and he give the person prayers.
Iworika (3).
a.Ese ifa:
Iwori Ayoka a difa fun Oka to se omo elewo bobo won ni
ki o rubo, nitori arun inu ati wipe ise oju ko nise,
Oka rubo ki o ri ifa, ko rubo arun inu re, ti inu ba
gbe Oka won ma ni opebu ojukan ti o ba joko ni ounje
ma wa ba nibe, sugbon ko ru ebo arun inu, oun lo ma ba
Oka ja di oni yi, ifa ni eni to ba da ifa yi ko rubo
nitori arun inu re ati wipe ise oju kan nise onitoun.
Aso molamola are re lebo, akuko 3, eyele 1, eku 3, eja
3.
Words of ifa verse:
Iwori ayoka predicted ifa divination for Oka the child
of elewu bobo, they said Oka should perform perform
sacrifice because of running stomach but Oka refuse
oka only perform sacrifice to be fortune, since where
Oka sit anything that Oka like to eat will surely meet
Oka at the place and Oka always suffer from running
stomach, ifa said the person that divine iwori Ayoka
should perform sacrifice because of running stomach
and that person work will be one place.
b.Ikilo ifa:
Ifa ni eni ti o difa yi ki o rubo tori arun inu ati

wipe ise ojukan ni ise re.


Ifa instruction:
Ifa said the person that divine Iwori Ayoka should
perform sacrifice because of running stomach and the
person will be one place.
c.Nkan ebo:
Aso molamola, akuko 3, eyele 1, eku 3, eja 3
Materials and animals
Multicolours dress, 3 cork, pigeon 1, rat 3, fish 3.
d.Aladimu:
Ifa ni aladimu ti a o bo pelu obi.
Offering:
The person will worship ifa with kolanut.
e.Pipese nkan ebo:
Babalawo yi o ba eni ti o difa yi bo ifa pelu oun ebo
ti won ti pese sile, yoo si wure fun lopolopo.
Method to prepare the medicine
The ifa priest will assist the client to perform
sacrifice to ifa and he give the person prayers.
Iworika (4).
a.Ese ifa:
Iwori karakara adifa fun igba to nwa alatunse won ni
ebo ni ki oro pe a ri alatunse pe ko ni jina si rara
ati wipe ile eni nla ni won ti nki yan layo, igba rubo
oru, ewe epin, ose dudu, akuko 1, ayebo 1, eyele 1,
obe ike 2, ni o fi rubo, obe naa ni won n tun igba se
loni ni won fi ma nfin igba lara, ifa ni eniti o difa
yi ko rubo pe a di eni apesin a tun ri alatunse.
Words of ifa verse:
Iwori karakara predicted ifa divination for calabash,
that is looking for someone that will dress for him,
they said calabash should perform sacrifice that
Calabash will not lacked the person that will dress
him, and that they will be used calabash in the house
of riches. Epin leaf, local soap, 1 cork, 1 she hen,
1 pigeon, small leaves 2, after the sacrifice this
knife is used to dress for Calabash, ifa said the
person that divine iwori Ayoka should perform
sacrifice to become an important person and the person

will has many followers.


b.Ikilo ifa
Ifa ni eni ti o da ifa yi ki o rubo ki o le ri
alatunse ati wipe eni yi o di apesin laye.
Ifa instruction:
Ifa said the person that divine Iwori-Ayoka should
perform sacrifice to make the person become important
and the person will control a lot of people
c.Nkan ebo:
Ewe epin, ose dudu, akuko 1, ayebo 1, eyele 1, obe ike
2.
Materials and animals:
Epin leaf, local soap, 1 cork, 1 she hen, pigeon 1,
small knives 2.
d.Aladimu:
Ifa ni aladimu ti a o bo pelu oti, obi ati ayebo kan
Offering:
The person will worship ifa with kolanut , wine and
she hen
e.Pipese nkan ebo:
Babalawo yi o ba eni ti o difa yi bo ifa pelu oun ebo
ti won ti pese sile, yoo si wure fun lopolopo.
Method to prepare the medicine
The ifa priest will assist the client to perform

Potrebbero piacerti anche