Sei sulla pagina 1di 33

Iba oo!

Iba atiwaye ojo!


Iba atiwo oorun!
Ibaa baba!
Iba yeye!
Iba Oluwo!
Iba Odungbona!
Iba Kiridi Awo Id ita !
Iba Agboruku Awo Ile Ife!
Iba Afikanimun fo fin-in-fin-in Awo Oloyemoyin
Ifa dakun oo!
Orunmila dabo!
Amonjo alasie maa tan
Onle oroke omo Owole!
Amongba eniyan yanpin
Onile Oroke omo Owoleji
Oro asoso mo tii
Kin in kin-in Eye okun
Sapata ebo loju ona
Eegun Oluufe tii son monriwoo pako
llAdabo
Ose Otura (1)

Ose Otua iwo loo saaju ebo , Iwo loo sii kanyin
ebo
To ni Oluwo
Tufee ni Odugbona
Oro kan
Oro Kan
Eyi ti Babalawo b aso sile a degub lailai
Ase ale ase oworo
A d fn argb abor kokooko
Nijo ti n lo ree ba won naja ojugboromekun
Won larugbo oloso
O oloun loso
Won larugboo lajee
O loun o lajee
O nin sugbon oun lafose lenu
Nje eni t oba sun ko d ide
Igba Akuko n daja
Eni o ba sun ko d ide
2. wnrn ajise (wnrn br)
Otun awo Aba
Oun lo sefa fun won lode Aba

Osi awo abose


Oun lo sefa fun won lode abose
Atotun
Atosi
Won kii
Sebo ai mo da
A dia fun asewele
Eyi tii
Somokunrin Idepenu
Nijo ti won n gbe woon regbo agbewure
Won ni ko nii de
Won ni ko nii bo
Won leboo re o nii se
Ifa niro ni won n pa

E baa degun depe lelebo lori


Ko lee j
Egun iyan kiri modo
Egun isu kii mobe
Tatelesi kii um ona
Egun ara orun kii mara aye
Sawarepepe
Epe moo belepe lo o
Sawarepepe
Asewele de mo ni depenu

Sawarepepe
Epe moo belepe lo o
Nijo tewure ba boju weyin nii fepe felepe
Sawarepepe
Epe moo belepe o
Sawarepepe.
Iwure: Ifa dakun Orunmila dabo! Bi eni to dafa
yii b alo sajo, je ko dele layo lalaafia ma
Iwure : Ki egun elegun epe elep o mo lee um
lagbaja yii o.

Ose Otura(2)
Bolu b alo! Olu nii sin in Osetura waa ba ni
lase si elo yii
Atepo
Arepo
Awon me jeeji ni won jojo faakara n uwo
A d ifa fun f ejerindilogun orodo

Nijo ti won n gbegbo lo sode orun


A d ifa fun Osetura
Eyi ti n ba won gbebo lo sode orun
O gbo riru ebo o ru
O gbo Eeru o si tii eeru
Nje taa lo tete gbegbo de bode
Ose Otura
Ose Otura lo tete gbegbo de bode
Iwmo Akinoso
Ose Oninare
Ose awurela je K ebo o fin
Iwure : Ifa je k ebo yii o fin je keeru o da.

Eji Ogbe
Eji Ogbe dakun dabo fiye denu koo fiye dekun
A kii Gboju ka f oloja jeri ejo
Ifa laa mo o f oloja jeri ejo
Sugbon iro laa gbodo p amo on
Agunmonna Awo eba ona
Oun lo d Ifa fun seboosoosa

Eyi tii s elegbaa eni


Awa s oosa
Ifa waari aregbaa eni
Iwure Orunmila waa so lomonrin
Di olopolopo
Eni l ode isalaye , ki won O maa ran-an lowo

Okaran Meji
Okaran Meji , ebo yii ti di eboo re koo bani se
dandan koo segun awon otaa re
Okanran kan nihiin
Okanran kan lohuun
Okanran me jeeji a bidi jogodo
A d ifa fun Oya ti n sunkun omo rele onira
Ebo lo se ko too lo

Eyin omo Oya da?


Awa ree heehe
Iwure: Ifa dakun dabo fiye denu
Pese omo rere fun-um l ode Isala

Owonrin S Ogbe
Esu peere jegede!
Egba peere jegede!
A d Ifa fun Ologeeesa
Eyi ti o koro leje tomotomo
Ebo araye ni won ni ko waa se
Eje awa koro awa o ku mo
A dewee j ogbo
Eje awa momo koro
Iwure: Ifa je ki eje lagbaja koro lenu oso lenu
aje lenu eleboloogun

Obara B Ogbe
Obara B Ogbe ! ebo yii di tire, koo je k ebo o
fin ki eru o da ko dode orun ko se si toloore
Itan Ega o see salejo
A d ifa fun Ajankoorodugbe
Eyi ti n sawo rele Elewii
Awa rubo
Eboda na o
A momo s ebo ajankoorodugbe Ifa wa se
Iwure : Ifa je ki ebo yii fin koo je ko da ko
dode orun ko se si tolore

Aworan o loju ekun


A dia fien Latoose omo arole
Sigidi o yirun pada
A dia fun siinrinkusin omo Osun
Ope eluju abimo gudugudu
A dia fun soorowo omo yami Aje
Oju wonu ibu o jokoo
A dia fun karubo ko da omo Elegbara
N je baa la f eku rubo je ko moo fin
Siinrinkusin
Ifa jebo o da felebo
Siinrinkusin
Baa ba f eja rubo je ko moo fin
Siinrinkusin
Ifa jebo o da felebo
Siinrinkusin

Iworin W Ofun (1)


Iwure: W Ofun agbaagijan omo Iburu ; Ifa je k
ebo yii o fin Ketutu yii o gba
Iwori towofun towofun!
Iwori tesefun tesefun!
Iwori tagbede me jeeji fun seruseru
A d ifa fun Agbado ti n roko a i lero lodun
Ihooho dodo lagbado roko
Bo ba d igba abo
A donigba aso
Ihooho dodo lagbado roko
Boa ba d igba abo
A donigba omo
Iwure: ifa dakun ma jee ki lagbaja o wa owo ti
nigba kookan, ma jee ko wa aya ti, ma jee ko
wa oko ti ati ire gbogbo to ku

Iwori W Ofun (2)


Agbaarin nii foju iran wape
A dia fun Erelu
Erelu tii se yeye owon
Afoolanu akala
A dia fun Owon
Eyi ti o yo toko bo
Yoo pabi Iya e da kalele o too le
N je ibi laa f Owon
Owon so o dire o
Ibi ti a f Owon

(10) Ika Meji


Ika meji dakun o ! ebo yii ti di ebo re, k ebo fin
keru o da ko dode Orun ko se si tolore.
Okan gbaa nibuu
Okan gbaa niroo
A d ifa fun Aase gbangba
Nijo ti n rogun Ilurin
Ebo ni won ni ko se ko too lo
O gbegbo o s ebo
O gbeeru
O tu eeru
N je bi Aase ba gbirin tan araa o maa je funum
Iwure: Ifa je ki ajinde ara o maa je fun-um.

(11) Irete Meji (1)

Irete Meji koo wa koo ba ni lase s ebo maa


Iwo o te
Emi o te
Ote di meji
O dododo
Awon lo d ifa fun Aloriire ma lese ire
Ibi Ori n gbe mi ire
Ese mo mo si ibe
Dakun dabo
Irete Meji (2)
Pa Igunnugun b ofa
Awo won nle Alara
Pa awodi bo Ose
Awo oke ijero
Pa Atioro Bogun
Awa araka ni mode
Agbonmi nii wole eja
Apajuba nii bile aparo wo
Olugbongbo tiila
Ni won fi n segun ogulutu

A dia fun layigbo ogege


Ti won mole iku e tan laye
Won n pilee torun
Ifa lo domimi mi ogege
Ela ba ni wole orun
Barapetu ba wa tun taye mo
A bu won lorun awa o w amo
Iwariwari orun
Ota a bori poogodo
Ile iku mo n wo lorun
Ogerere ile iku mo n wo lorun
Ko ni bu o layigbo
Arundu o ko nii bu o layigbo
Arudu
Iwure: ibi reere ni koo gbe e de, esse e re,
dabo ma si ibi rere , mama s ina
12 Ogunda Masa (1)
Ogunda Masa, ebo yii mama di ti re, koo ba ni
se dandan, Saa reere ti lamonrin nda , je ko
was si imuse
Ogunda saa saa

A dia fun Alaasa


A bu fun Onikahun
Nijo won n baraa won sore atilewa lailai
Won a ni kanhun mo ti dabaku aasa ojo tipe
Ogunda Masa (2)
Abayin igbo nii mori pijegi
Babalawo Oge lo sefa fun Oge
Oge n tikole orun bo waye
Nje omode kii motaa poge
Eyin Oge lota ti yaa bale
Ibi se mi
Ibi se mi l Oge n ke
Iwure : Ifa dakun dabo fiye denu koo dekun
Oolore re, ifa ma je ko jinna si
13 Otura tukaa (otura Ika)
O tu raka
O rin raka
Erigi l awo Agbasa
A d ifa fun won ni Seese-agere
Nibi won ti ji ti won ti n wa ohun ebo kin
Won tun ko ohun ebo sile tan

Won tun n wa alawoo kiri


Owo ti n be nile yi
Ohun ebo nii se
Erigi l awo Agbasa, Ifa a rohun ebo
Agabado ti n be nile yi ohun ebo nii se
Erigi l awo Agbasa, Ifa a rohun ebo
Iwure: Ifa gbogbo ohun ebo ti o toju kale yii je ko
dorun , a fowo omode ru u, ki won o fowo
agbalagba.

Irosun Opinmi (1)


Ifa dakun dabo, ifa je k ebo yii o dalade orun , koo je
ko fin ko da ko dalade orun
Eekanna wiin wiin
Awo Emil o d ifa fun emi
Emi tu soloja ninu ara

Ebo ni won ni ko waa se


O gbebo nbe
O s ebo
O ogbo eeru o tu eereu
Kohun kohun mo se Emi oloja ara
Ohun o gbodo sEmi re o bo ni kekere
Iwure: Ifa ma je ki emi re o bo ni Kekere

(2)

A bu si tun yin
A dia fu nojo
Ojo tii o sai tun fi yin in leyinwa
Nje a bu si tun yin
Ojo loko agbado
A bu si tun yin

Iwure: Ifa ma je ki emi re o bo ni kekere.

15 Ogundabede (1)
Ogundabede, iwo loo da ebo ni Igara ti o kii je ki
ebo o fin
Iwo loo da etutu ni Igara ti kii fii gba won ni iru ebo
won ni??
Oni ebo ti won o ba ti pe o si ni, a pe o si ebo (nome
of odu casted in divination) ni koo dabo ki o ba ni
gbe ebo yii lo si ode orun, ko fin ko da, a fowo omo
kekere ruu, ki o waa fowo agbalagba agbaa
Eniyan ti ko lowo lowo

Won a d ifa eniyan lasan


A d ifa fun alake ile egbe
Niggba ti n be laarin iponju
Ebo ni won ni ko waa se
O gbebo
O rubo
O gbo eeru
Orunmila ogbolu me siare o ri
Ifa awo ki ti n se loro gangan

Ogundabede (2)
Bd
Awo won lode Ipo
Awe
Awo ode Ijesa
Ominrinminrin ara iramori
Igi ganganran mose gun mi loje
Olorun d ebiti oran kale
A kii ralawo si rejereje
Awon lo dia fun Olofin
Nijo ti won k ebo keedi ti oun

Olofin ni ki won o mase k eo


Keedi ti oun
Orogbo kan
Oduso kan
Bomode ba kokin gagaaga
A f Oduso sile
Esun o pelesuun
Ere o peleree
Ogundu ogan
Ni o jin lori araa re
Araa won ni won o moo jin
Araa won ni won o moo gbonrangandan
Gbogbo awon ti n ba lagbaja sota
Gbogbo awon (nome do cliente ou meu) ki won o
moo ku gbonrangandan
Iwure J ki gbogbo awn t ti yi eniyan ti kuna si
isal ki o si k
Que todos os inimigos desta pessoa cair e morrer.
16 Okanran Oyeku , Ifa bani yeku lorii lamonrin
Okan yeeyee
A d Ifa fun Olugun awerooro
Omo Aleku gori odi lo

Ebo ogbo n won ni ko waa se


O gbebo n be
O rubo
O gbo eeru
O tu eeru
Ifa ba leku lo nigba yi awa o ku mo
A momo s ebo Okanran yeeyee
Ifa ti ba wa lebi lo
Iwure: Ifa leku lo fun-un, le arun lo fun-un
Oseroyin (Osewori)
Oseroiyn (1)
Iwure : ifa dakun dabo fiye denun fiye dekun bani
royin ebo yii
lalade orun
Oke le gege mo ye
A di ifa fun libi tii s omo ogun
Ad ifa fun Libi tii s omo ija
A d ifa fun Libilibi tii s omo Osoosi
Nijo ti won jo n roko ode
Ebo ni won ni won o waa se

Won gbebo nle


Won rubo
Won gbo eeru
Won tu eeru
Nje libi perin o perin
Libi perin
Libilibi perin perin
Iwure: Ifa ise ti ba n se mo je ki o di . Ise moo n
lowo, Ifa je ki ona o la fun-un

Oseroyin (2)
Bomode ba mosee je
Won a jonize
Bi won o si moo e
Won a je Oluse
Ise lawa ti n je f oba awa lailai
A d ia fun Oba oropo iyun eyi ti n lo ree jise ola
feebo
Nje jeere o
Ose Pawori
Jeere o
Bo ba dele koo jise owo

Koo jise omo


Jeere Ose Pawori
Jeere

Ose Otura(3)
Osetura pele oo! Awurela Akinnoso! Bo oba saaju
ebo si kanhin ebo
Ose ni won n peja nile alake
Okiribojo lomi Ilawe
Bojo ba ro lodi l eso
Eja gborogboro a maa lorun bo waye
Ope a bifo jinginni
A d ifa fun won n ile Ilose
A bu tun won n ile Ejigan
Won n won o rubo ki won o lee lowo n ile Ilose
Won n won o rubo ki won o lee bimo lemo n ile
Ejigan
Awon mejeeji lo rubo
Ilose laa pe Ijebu
Ejigan laa pe Ile-Ife oodaye
Orunmila je ki lamonrin lowo bi ara Ilose laye

Baba koo je o bimo bi ara IleEjigan.

OseOtura (4)
Ose Otura gba a tete
Ajikansee lekun
A dia fun akilolo ti n gbegbo r ode orun
A pe emi ni mo mo mo mo ko ko ko debi yii
Ebo toun ni ko te te te te te da
Ebo toun ni ko te te te te te fin
Riru ebo eeru atu Esu
Aye ye wa tuturu
Ou
Ose Otura bba a tete
Ajikansee lekun

Ogbe Tomopon (Ogbe Oturupon)


Ogbe tomo pon
Ogbe sunmo si
B m oba n sunkun
Iya laa kee si
A dia fun Agan o ribi ile Ife
Eyi ti n sofon gbaja gbaja lori ebo
Won ni e e mo pe lenu elebo
N lebo gbee fin
Lenu elebo
Leboo gbee d.
Iwure:
Osanwo iku
O sanwo arun
O sanwo ofo
O sanwo gbogbo ajogun

Okanran Osa (2)

Iye Okanran Osa i i bebo o mo fin


Iye Okanran Osa i i bebo ai mo da
Okanran sale koo sakuuta
Awo Oko lo d ifa fun Oko
Won ni o sa kaale ebo ni o se
Oko gbebo nbe o rubo
Okanran sale koo sakuuta
Awo Aso lo d ifa fun Aso
Won ni o as kaale ebo ni o se
Oko gbebo nbe o rubo
Okanran sale koo sakuuta
Awo Aso lo d ifa fub Aso
Won ni o sa kaale ebo ni o se
Aso gbebo nbe o rubo Okanran sale koo satuuta
Awo Il elo d ifa fun Ile
Won ni o as iku ara are.

1 If chanting one stanza, chant this prayer at the


end of stanza. But if two or all three stanzas of
knrn s are chanted, say this prayer at the end
of the second or third stanza. In addition, as this
prayer is said, the yrsn of knrn s on the
Ifa tray is sprinkled on the sacrifice.

Ile gbebo nbe o rubo


Eboo won la i i gboku oko
A i i gbo iku Aso
A i i sii gbo iku Ile
Ase bo gbo
Iwure : Ifa ti lamonrin ba lo si egbe je ko dele layo
lalaafia. Ifa ma je ko ri idana aburu .

Okanran Osa (3)


Iye Okanran osa i i bebo o mo fin
Iye Okanran Osa I i bebo o mo da
Ka um gege lu gege
Awo ile Alakooko
Igbin ko lara ina ni yiya
Awodi o pa saa gbadie aja
Olewo meje

Imoran mefa
Oran ti won mo moo mo
Ti won o leem o tan
N ni won n difaa si
A dia fun Olu
Nijo ti n gboguun lo ilu gbendu gbendu
Esin gagaagan nwaju olu
Oko gagaagan leyin re
Ogun ti won fesin foko j
Eyi ti won o lee se
Iruke bayii n ifa fii tumoo re
( the babalawo would use his right hand or rkre
(cow tail) to fan the top of the sacrifice)
Tumo iku fun-um
Tumo arun fun-um
Tumo Ofo fun-um
Tumo gbogbo ajogun fun-um
Iwure : Ifa ti lamonrin ba lo si egbe je ko dele layo
lalaafia. Ifa ma je ko ri idana aburu .
1.After the Iyerosun of Okanran Osa is sprinkled on
the sacrifice, chant the following the prayer.
Iwure: Emeta laa k Eruku f Oloja
(its is three times that we give Eruku to Oloja)

2 The sacrifice is then used to touch his right and


left ears; we shall say:
Iwure : Ifa ma je ki o fie ti otun gbo aasan, ma jki o
fie ti osi gbo igede, ki haa o ma ti enuu re bo
Prayer :Ifa please do not allow him to use his right
ear to hear aasan . Do not allow his left ear to hear
igede. Let him exclaim in sadness because of
anything.
3 we raise the sacrifice toward the mouth of the
cliente ; and ask the cliente to blow on the sacrifice
(x3) three times we then say
Iwure : Aje o nii je ohun re o!
Prayer : may the witches not up your voice.
4) Now add dirt or sand from the Earth and say the
following two
Prayers
Iwure : Ile ti won ba ni lagbaja o rubo, koo pe o ru, ti
won ba so pe ko tu, koo pe o tu. A a fi o rubo eri laa
fi o se
Prayer: mother Earth, if anyone says this cliente did
not offer sacrifice, testify that he did ; and if they

said he did not give the free booties , tell them he


gave it, we did not offer up as sacrifice, but we
only added you to bear witness
Iwure: Abudi, Awo Ile, lo d ifa fun Ile omode kii bule
ko mo di Agbalagba kii bule ko mo di
Preyer:
Abudi, the Babalawo of the Mother Earth, cast
divination for the Mother Earth.
Children would not scoop sand without overing it up
again.
Elders cannot scoop the Mother Earth without
covering it up again.
5) Now ask Ifa where or what location destination
the sacrifice must be taken.
VII Adimu:
1)The cliente is asked to kneel in front of the
Babalawo and use both of his hands to cover
either the opele or Ajere Ifa,. As the cliente does
this, say the following praye.
Ose Mefon(Ose Oturupon)
Adimu ogbo
Adimu ato
Erin di o um o ya aso.

Efon di o um o yanjana.
Agbanrere di o um o l awo l ori sanransanran
A dia fun waagbani tiii s omo Olopa ororo
O f eegun ile segbeje
O f oosa ibe segbefa
O ni kaka k oun o ti waa yan Edu um ope di o um
Koo mo yin mi nu
Iyere ara igi nii won
Tara ope kii won danu
Eniyan kii as go r ope kiku o ji
Oluwaa rep a!
Iwure:
Nijo l iku n bo, k ifa o bo o
Nijo arun n bo, k ifa o bo o
Nijo ofo n bo, k ifa o bo o
Nijo ija n bo, k ifa o bo o
Nijo ese n bo, k ifa o bo o
Nijo egba n bo, k ifa o bo o
Nijo gbogbo ajogun n bo o bo o
Sugbon nijo t ire aje, ire aya, pipe l aye, gbogbo ire
ba de k ifa o si o s ile.

2)After this, the person is asked to open his palms ;


the Babalawo would use his reght hand to
through the bridge of the two hands say:
3)To!
4)Alaja lese n lana.

Potrebbero piacerti anche